E wa w'oju Omolola to nilo iranlowo Gomina ipinle Ogun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, September 5, 2022

E wa w'oju Omolola to nilo iranlowo Gomina ipinle Ogun

O ti pe die ti Arabinrin Omolola Ogunlaja ti nilo iranlowo awon eleyinju Aanu kaakiri agbaye,ti omo Bibi ilu Ijebu igbo naa si ti wa n be Gomina ipinle Ogun iyen Omooba Dapo Abiodun lati nawo iranlowo owo fun omo odun mejilelogbon naa.
Ise ransoranso ni arewa obinrin yii yan laayo,to si n se daadaa sugbon to nijamba oko lori okada losu keji odun 2019,awon molebi ati awon obi e ti ta Ile atopo dukia ,beeni won ti sise Abe lemeeji otooto nileiwosan ijoba ati to aladani kan nipinle Eko ati Ogun sibe ko siyato beeni ko le fi ese naa rin.
Ni bayii, Omolola niilo owo to le ni milloonu meedogun lati lo fi sise Abe Lorile ede India ko le rin daadaa,apapo awon oniroyin kaakiri Orile ede yii wa n be Gomina omoluabi wa nipinle Ogun lati ran omo yii lowo,
Akanti te o ba fi owo si ni,0725374928 gtbank Omolola Ogunlaja,foonu nomba re ni,07035491920.
E Seun pupo e ranti pe, enikeni ti Iwo ba le se iranlowo fun ni enikeni e,Gomina wa nipinle Ogun ati eyin eleyinju Aanu kaakiri agbaye e jowo e ran arewa yii lowo,e Seun.


No comments:

Post a Comment

Pages