Oba Orin yoo pada sorile ede yii l'ose yii,ni eru wa n ba awon olorin Fuji - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, September 5, 2022

Oba Orin yoo pada sorile ede yii l'ose yii,ni eru wa n ba awon olorin Fuji

Bi e se n ka iroyin yii,idaniloju wa pe, Alagbede Orin Iyen Saheed Akorede Osupa omo Okunola yoo bale sorile ede yii ni opin ose ,gege bi iroyin tojubole se gbo pe awon ololufe oba Orin ti n reti re lati tun maa fi Orin alaadun da won lara ya.
Osu keta odun yii ni obanla oba Orin rinrin ajo lo si Orile ede America,to si n se daadaa nibe'baba Oni dola'gege bii inagije re tuntun ti gbon opolopo dola iyen owo ti won n na Lorile ede America s'apo daadaa.Koda a gbo pe Olufimo akoko ti gba iwe igbelu beeni omo Bibi ilu Ibadan naa ti le wole jade gege bo se fe.
Aimoye ohun meremere ti omo Okunola ti se latigba to ti lo sorile ede America nitori o n ri ode ere gba daadaa,Koda Olufimo akoko tun gba America lo si Canada to si 'gbon opolopo dola s'apo nibe naa.
Ni bayii ti oba Orin ti fe de pada a gbo pe eru ti n ba awon akeegbe re nidi Orin Fuji nitori won mo pe ti 'ologini ba de,o di dandan ki awon ekute kekeeke para mo.


No comments:

Post a Comment

Pages