Owo te awon ajinigbe meta nim'eko nipinle Ogun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, September 6, 2022

Owo te awon ajinigbe meta nim'eko nipinle Ogun

Owo iko awon Olopaa ati ajo Amotekun ti te awon ajinigbe meta yii lagbegbe Iwoye nilu Imeko Afon nipinle Ogun,oruko awon meta ti owo te naa ni,Aliu Abubakar eni odun mokandinlogbon,Umar Tukur eni odun merinlelogun ati Yay Isah eni odun marundinlogbon.
Oga olopaa ipinle naa Lanre Bankole fidi isele naa mule to si so pe won ti ko awon odaran naa lo si eka to n ri si iwa odaran nipinle Ogun


No comments:

Post a Comment

Pages