Ope o!Ooni Ile Ife ti segbeyawo pelu obinrin mi-in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, September 7, 2022

Ope o!Ooni Ile Ife ti segbeyawo pelu obinrin mi-in

Mariam Anako to je omo Bibi ipinle Kogi ni iyawo tuntun l'aafin Ooni Ile Ife,Oba Ogunwusi ti se igbeyawo bonkele pelu omo Bibi ilu Ebira naa leyin ti igbeyawo re daru pelu Olori Wuraola.


No comments:

Post a Comment

Pages