Leyin ojo die ti oba alade naa segbeyawo pelu Olori Mariam Anako iyen leyin osu die tigbeyawo re pelu Olori Shilekunola daru.A gbo pe Agbegbe Magodo nipinle Eko ni Arabinrin Opeoluwa n gbe,sugbon ti enikeni ko ti i le so boya loooto ni Ori Ade naa yoo tun segbeyawo pelu omo Bibi ipinle Ondo naa.


No comments:
Post a Comment