Omoge gbemi ara e nitori afesona e segbeyawo pelu obinrin mi in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, September 13, 2022

Omoge gbemi ara e nitori afesona e segbeyawo pelu obinrin mi in

Odunayo Olaitan Adonis loruko arewa obinrin te n wo aworan e yii,agbegbe Ijeshatedo nisele naa ti sele lose to koja nigbati afesona e to n je Ola Saheed lo segbeyawo pelu obinrin mi in,Koda owo oloogbe ni okunrin yii fi segbeyawo,iyen lo mu arewa obinrin yii gbemi ara e,to si fi obi,atomo odun meje to n je Lekan saye lo


No comments:

Post a Comment

Pages