Emi odo meta lo ba isele naa lo latowo Oloye Socopao to je ore timotimo si Oluaye Fuji iyen Alaaji Wasiu Ayinde.Ibinu yii lo mu awon odo Dana sun Ile Oloye Adigun koda oko ayokele to le ni meje ni won dana sun pelu Ile alaranbara re to wa nilu Agosasa.
Agbenuso olopaa ipinle Ogun iyen Oyeyemi Abimbola fidi isele naa mule to si so pe oun atawon iko oun setan lati je ki alaafia joba lagbegbe naa


No comments:
Post a Comment