Ilu Agosasa ti daru,opo emi ati dukia lo Sonu,Oye oba ilu naa lo dija sile - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Tuesday, September 13, 2022

Ilu Agosasa ti daru,opo emi ati dukia lo Sonu,Oye oba ilu naa lo dija sile

Osu die loba ana nilu Agosasa nitosi Ipokia nipinle Ogun waja,iyen oba James Elegbede leyin ti awon afobaje fenu ko pe,Ogbeni Sunday Okosun ni ifa mu la gbo pe Oloye Adigun Akeem eniti awon eeyan maa n pe ni Socopao dide pe oun nife lati di oba ilu naa.Oloye yii to sunmo Gomina ipinle Ogun iyen Omooba Dapo Abiodun la gbo pe o doju ija ko awon odo ilu ti won tako ero re lati di oba.
Emi odo meta lo ba isele naa lo latowo Oloye Socopao to je ore timotimo si Oluaye Fuji iyen Alaaji Wasiu Ayinde.Ibinu yii lo mu awon odo Dana sun Ile Oloye Adigun koda oko ayokele to le ni meje ni won dana sun pelu Ile alaranbara re to wa nilu Agosasa.
Agbenuso olopaa ipinle Ogun iyen Oyeyemi Abimbola fidi isele naa mule to si so pe oun atawon iko oun setan lati je ki alaafia joba lagbegbe naa


No comments:

Post a Comment

Pages