O ma wa ga bayii o,Gomina Akeredolu pase pe ki won yo oba Irele nipo oba - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, September 1, 2022

O ma wa ga bayii o,Gomina Akeredolu pase pe ki won yo oba Irele nipo oba

Oba Idowu ni Gomina nipinle Ondo iyen Ogbeni Akeredolu ti pase pe ki won yo o loye kuro nipo oba Irele nipinle naa, Akeredolu so pe,oba alade yii ko gboran bee lo n se awon ohun to tapa so ofin gege bii oba ilu naa.


No comments:

Post a Comment

Pages