Odu ni oloogbe Oloye Olatunji Jacob Gbesabi eniti opo eeyan mo si Baba Oselu nilu Eruwa baba naa ki n se aimoye f'oloko.
Odun 1934 ni won bi Oloye Gbesabi ,baba kawe beeni baba fi opo omo ati omo omo saye lo.okan ninu won ni dokita Samuel Gbesabi to je osise ileese redio fresh fm to je ti Oloye Yinka Ayefele.
Ayeye asale Orin fun Oloogbe Gbesabi yoo waye ni adugbo Oselu nitosi Oke Ola Eruwa,eto isinku yoo waye ni St Mary Catholic Church Sango Eruwa nigba ti jije mimu yoo waye Nile ni agbegbe Poli Adeseun Ogundoyin Eruwa.


No comments:
Post a Comment