Ori ko Dunsin Oyekan olorin emi yo ninu ijamba oko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, September 4, 2022

Ori ko Dunsin Oyekan olorin emi yo ninu ijamba oko

Oju ona Eko si Ibadan ni ijamba oko naa to sele lose to koja to si je pe Olorun nikan lo ko akorin emi nni Dunsi Oyekan to padanu iyawo e lodun die seyin yo sugbon okan ninu awon omoose e farapa ti iyen si ti n gba iwosan nileiwosan kan nipinle Eko.


No comments:

Post a Comment

Pages