Oba Alade fi ese yo oju Wasiu,esun pe o n ba Olori oun jo loju agbo ariya lo fi kan an - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, October 7, 2022

Oba Alade fi ese yo oju Wasiu,esun pe o n ba Olori oun jo loju agbo ariya lo fi kan an

Oba Nureni Oduwaye to je okan ninu awon oba ni agbegbe kan nitosi Sagamu nipinle Ogun ti fi ipa ati ese yo oju onisowo okunrin kan to n je Wasiu Oduwole nitosi Sagamu nipinle Ogun.
Esun pe Wasiu n ba Olori laafin oun jo loju agbo lode Ariya ayeye ojo ibi obinrin kan to n je 'iyalaje lo fi kan an
Oju ese la gbo pe oju okunrin yii yo sita sobolo ti won si ti gbe e lo sile iwosan fun itoju.


No comments:

Post a Comment

Pages