Patience,aburo Mercy Aigbe dana sun dukia iya won,esun pe o ti ra kadara awon omo to ku fun Mercy lo fi kan iya naa - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, October 7, 2022

Patience,aburo Mercy Aigbe dana sun dukia iya won,esun pe o ti ra kadara awon omo to ku fun Mercy lo fi kan iya naa

Ariwo pe aje ni iya awon ni aburo gbajumo oseretiata obinrin nni iyen Mercy Aigbe n pa kiri, Patience aburo Mercy lo so pe,iya awon ti lo aisiki awon omo re toku fun Mercy nikan soso eyi lo mu Patience tina bo Ile iya naa , opelope awon panapana to tete de ibi isele ohun.


No comments:

Post a Comment

Pages