Biola Adekunle pariwo sita pe 'integrity film je oun lowo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, December 29, 2022

Biola Adekunle pariwo sita pe 'integrity film je oun lowo

Biola Adekunle to je gbajumo oseretiata obinrin ti so pe,Alase ileese integrity film je oun ni owo lati odun merin seyin,bee lo n be awon Ololufe fiimu agbelewo pe ki won ba oun be 'Busayo to ni ileese integrity ni Arena nilu Osodi lati da milioonu kan to je oun pada ki oun le ri owo fi ya fiimu.


No comments:

Post a Comment

Pages