Fuji Template lakole Orin ti olori ebi Olufimo gbe jade nibi to ti so itumo 'orin Fuji ,oba Orin so pe Orin Fuji je onje adidun bii iresi dindin ati salaadi.
Osupa ti irawo re n tan daadaa laarin awon onifuji lasiko yii tun korin oriyin lati fi ki oloogbe Alaaji Sikiru Ayinde Barrister fun ipa ribiribi ti oludasile Fuji ko nigba aye re
Idi eyi lopo awon eeyan se n pe Osupa ni 'oosa Fuji nitori ko si Orin re ti ko ba igba ati asiko mu rara, tojubole tu gbo pe Ogbeni Aremu iyen Arems ti fun Osupa ni oruko tuntun bayii,(G.O.A.T) itumo e ni pe gbogbo Orin Akorede Tasansan,bee lo n ba igba mu.


No comments:
Post a Comment