Afefe Oro ati iyawo Ifankaleluya lo n sojo ibi Loni in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, January 2, 2023

Afefe Oro ati iyawo Ifankaleluya lo n sojo ibi Loni in

Gbogbo ojo keji osu kinni odun ni ayajo ojo ibi gbajumo sorosoro Ori redio nni iyen Aare Abiodun Adeoye AfefeOro ti omo Bibi ilu Abeokuta nipinle Ogun naa si n dupe lowo Olorun fun ipamo ati aabo re lori re.
Ohun to tun je ki ayeye ojo ibi naa larinrin ni pe,ojo kan na n ni AfefeOro ati iyawo ore re timotimo iyen Ogbeni Yomi Mate Ifankaleluya ni ayeye ojo ibi awon mejeeji, api baide tuu yuuu mama Beauty iyawo Ijebu, api baide tuu yuuu Afefe Oro emi eyin mejeeji a se opo odun laye.

No comments:

Post a Comment

Pages