Abe biriiji to wa ni Ajah nipinle Eko nisele buruku yii ti sele ti a si gbo pe oju ese ni won ti gbe oku e lo sile igbokupamosi kan ni agbegbe Yaba sugbon ti iko awon Olopaa to yinbon pa obinrin yii ti fese fe e.
Ile ijosin la gbo pe Oloogbe Bolanle Raheem ati Oko re ti n bo lojo odun keresi sugbon ti Olopaa kan to ti salo bayii yinbon fun obinrin to joko jeje niwaju oko ayokele baale re lojo odun.

No comments:
Post a Comment