Paul Oloye loruko oko Iyabo Ojo tuntun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, December 27, 2022

Paul Oloye loruko oko Iyabo Ojo tuntun

Gbogbo awon akeegbe oseretiata obinrin nni iyen Iyabo Ojo ni won ti n ki I ku oriire pe o ti pade Ololufe tuntun.Paul Oloye to maa n puromooti awon olorin loruko oko Iyabo naa,omo Ile Yibo ni sugbon ti Iyabo ti so pe okunrin naa n fi Ife han si oun daadaa.


No comments:

Post a Comment

Pages