O salaye pe Inu igbo ni ota ibon to pa Oloogbe ti jade wa beeni ko seni to ri oju awon to yinbon naa.O wa salaye Oloogbe bii eeyan gidi to feran lati maa ran awon mekuunu lowo.
Ogbeni to tun n korin takasufe atorin Fuji tun wa salaye pe,iwa ote ati aiferan ara eni denu po laarin opo awon agbaagba onifuji beeni pupo ninu won ko mu iwa oludasile Fuji iyen Oloogbe Alaaji Barrister rara nitori Oloogbe Barrister maa n fa owo awon onifuji kekeeke soke nigba aye re


No comments:
Post a Comment