Bi e se n ka iroyin yii ni tojubole gbo pe, Olori awon onimoto ipinle Eko iyen Alaaji Musiliu Oluomo ti yonda gareeji kan fun Seun Egbegbe iyen oko Toyin Abraham tele.
M.c so pe oun ko fe ki Seun to sese de lati ogba ewon tun pads sinu eebi re beeni oun fe ki Ogbeni yii maa ri owo toju molebi re.
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment