
Gege bi awon kan se n gbe iroyin naa Kiri pe, igbeyawo oseretiata obinrin nni iyen Wunmi Toriola naa tun ti daru,boya iro ni tabi ooto ni enikeni ko le so sugbon ti Wunmi funra e ti n fi Oro naa pa owe lori ikanni ayelujara re.Odun keta re e ti Wunmi segbeyawo pelu Ololufe re to je omo Bibi ilu Agbadarigi ti Olorun si fi omo Kan ta won lore.


No comments:
Post a Comment