Okiki Bright to tun yan ise Fuji laayo ti wa je ko di mimo pe,ika ati odaju ni opo ninu awon agbaagba nidi ise Fuji sugbon ti oun mo pe Olorun yoo se iyanu laye oun laipe nitori awon agbaagba nidi Fuji yii ko gbero rere sawon to n bo leyin beeni Oloogbe Sikiru Ayinde Barrister ko wu iru iwa yii rara nigba aye re
Ogbeni Raji Mutiu Ishola tawon eeyan mo si Okiki Bright ti so pe asoju ileese Megato ni oun nigba ti oloogbe Alaaji Fatai Oko Oloyun si wa nile aye sugbon okunrin naa kan feran ki oun ati e jo maa jade ni, nitori oun mo oko ayokele wa daadaa ni Oloogbe Oko Oloyun se feran kawon mejeeji jo maa jade,idi eyi lo se je pe lojo tisele aburu naa sele oun ni dereba to wa oloogbe lojo naa

No comments:
Post a Comment