Ki n iroyin mo pe,Oloye Ifatunde Apena fi ebun oko ayokele bogini ta Alaaji Sefiu Alao lore ti opo awon ololufe Orin Fuji si ba baba oko dupe, Tojubole ti sabewo si Ofiisi Alaaji Ifatunde ti omo Bibi ipinle Ogun naa si salaye fun wa pe,nitori Alao je egbon daadaa to tun maa n beere oun nigba gbogbo beeni ki n se nitori owo nikan ni Sefiu se feran oun sugbon alaafia oun ati molebi oun ni baba Oko maa n beere nigbakugba to ba pade oun nigboro
O tun salaye pe,Sefiu ko fi iseese sere rara beeni ko si ninu awon olorin Fuji ti won fi iwe mimo Kuraani ati Bibeli boju sugbon ti won n se oogun abenugongo labele.Idi eyi loun se feran Sefiu.

No comments:
Post a Comment