Yato si pe oludasile ileese yii je oloselu labe Asia egbe Apc ni Ilorin labe Gomina Abdul Rahman AbdulRasak,eyi lo tun je ko fi okan opo awon ololufe ileese God of Fulfillment bale nitori ijoba ti donate lu ileese naa lodun 2017 iyen leyin ti a da ileese yii sile lodun 2011
Eto lilo Jerusalem yoo bere ni ojo kejilelogun osu kerin odun yii,ti awon Ololufe won yoo si pada sorile ede yii ni ogbon ojo ,osu kerin odun yii
Awon ibi ti e o Ni anfaani lati de ni Isreal ni,Odo Jodaani,Kapaneemu,ite oba Solomon,oke Sinai,ite Lazaru ati beebeelo nigbati e o tun ni anfaani lati de Ijibiiti(Egypt) Cairo,Abu Tig Marina atawon ibo mi in,Ile itura to dara pelu aabo to peye wa fawon onibaara ileese God of Fulfillment
Ohun to tun je ki ileese yii tun yato ni pe,won n ta Ile lowo pooku,won le ba yin ra Ile,ileese won wa ni ilu Ilorin ,ti eyin ba fe ba won dowo pe ,e pe nomba won,07057432230,08035724138,08167289614


No comments:
Post a Comment