Omorapala fi omo f'oko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Thursday, February 9, 2023

Omorapala fi omo f'oko

Ojo kesan osu keji yii gan an ni oba asakasa iyen Alaaji Abass Akande Obesere fi omo re Cynthia Suliat Arike Gbemisola Ajalaruru fun oko,ti gbogbo awon Ololufe obaadan si peju sibi ayeye naa to waye ni Okota nipinle Eko

No comments:

Post a Comment

Pages