Nitori M.c Oluomo Dayo Amusa s'oko Oro si Iyabo Ojo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, February 26, 2023

Nitori M.c Oluomo Dayo Amusa s'oko Oro si Iyabo Ojo

Nitori Iyabo Ojo ko satileyin fun egbe oselu APC ,to si je pe egbe Lp lo ba lo nitori omo ibo ni ololufe re tuntun iyen Ogbeni Okoye,eyi lo mu Dayo Amusa so pe alaimoore ni Iyabo pelu bo se pe oga onimoto ilu Eko iyen Alaaji Musiliu Oluomo Akinsanya ni 'omoota'
Iyabo so pe tawon eeyan ba dibo fun egbe oselu APC,aye yoo gba awon omoota ju ti tele lo.Eyi lo mu Dayo so pe, alaimoore ni Iyabo nitori Oluulu iyen Alaaji Musiliu Oluomo ti se opo oore fun Iyabo Nipa sisanwo ileewe awon omo e atawon oore mi in
Ko pe ni Bimbo Akinsanya naa da soro yii pe,gbogbo won kuku ni Mc ti laago idi fun,sa o aarin Iyabo Ojo ati Dayo Amusa ko gun rege lasiko yii nitori Oro MC Oluomo


No comments:

Post a Comment

Pages