Oga o,won pa 'Oluomo danu nipinle Ondo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, February 26, 2023

Oga o,won pa 'Oluomo danu nipinle Ondo

Akinlabi Akinaso loruko Ogbeni ti a gbo pe awon eleso aabo pa danu nipinle Ondo lojo sannde,agbegbe Owena Ayetoro Idanre nisele naa ti sele,a gbo pe awon egbe oselu PDP lo n sise fun,gege bi a se gbo pe,o fe da ibi eto idibo ru ,leyin tawon eleso aabo ki i nilo ti ko gbo ni awon yen ba fun un nibon je


No comments:

Post a Comment

Pages