O mase o,won yinbon fun 'Oluomo nipinle Ondo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, February 27, 2023

O mase o,won yinbon fun 'Oluomo nipinle Ondo

Gege bi iroyin to te wa lowo se so pe,awon iko eleso aabo kan nipinle Ondo ti pa Ogbeni Akinlabi Akinaso eniti awon eeyan mo si Oluomo danu lojo sannde yii,egbe oselu PDP la gbo pe Oloogbe n satileyin fun sugbon ti a gbo pe o fe da ibi eto idibo ru leyin ti won kilo fun un ti ko gbo,ni won ba gbe ibon fun un je,to si ti gbabe soda sorun alakeji bayii


No comments:

Post a Comment

Pages