Alhaji Lanre Shittu,gbajumo onisowo oko ayokele ti ku o - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, February 27, 2023

Alhaji Lanre Shittu,gbajumo onisowo oko ayokele ti ku o


Aarin ojo Monde yii niroyin naa gba igboro pe,Alaaji Lanre Shittu ti papoda lati lo ba iyawo e iyen Alaaja Wuraola Shittu ,eni odun marunlelogota ni Oloogbe.

No comments:

Post a Comment

Pages