Aminat papapa iyen Bukola Adekogbe tun pe Adunni Ade ni oba awon asewo,o so pe gbogbo awon oseretiata to tele Oluulu iyen Alaaji Musiliu Oluomo ko se eyi nitori owo bikose nitori Ife tawon ni si I
Adunni Ade naa ti wa so pe,sebi nitori owo kekere ni gbogbo won se n ro lo odo egbe oselu APC ati pe pupo ninu awon oseretiata obinrin ni oga awon onimoto ipinle Eko ti gbaro nidi won

No comments:
Post a Comment