Won lo dibo ni o,ni won ba nijamba oko,oju ese lemi tokotaya naa bo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, February 27, 2023

Won lo dibo ni o,ni won ba nijamba oko,oju ese lemi tokotaya naa bo


Abule Romo nitosi Ganguwa nipinle Bauchi ni ijamba to mu emi oko atiyawo pelu aburo oko lo naa ti waye lale ojo satide nigbati won n bo lati ibi eto idibo pelu oko ayokele ti nomba re je,ABS620XA ati AG999JRE ,ki Olorun te won safefe ire

No comments:

Post a Comment

Pages