Ninu iroyin miiran la tun ti gbo pe,awon amokunseka kan tun ti gbemi siamaanu egbe oselu ApGA nipinle Ebonyi iyen Ogbeni Monday Idoko lojo toside ose yii,oun ni Alaga ijoba ibile Ishielu nipinle Ebonyi
Awon agbanipa kan ti sekupa Ogbeni Oyibo Chukwu to je omo egbe oselu Lp nipinle Enugu, leyin ti won gba emi e tan ni won tun dana sun un monu oko ayokele re

No comments:
Post a Comment