Owo iko Olopaa ti te molebi kan nan ti won n jale - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, February 18, 2023

Owo iko Olopaa ti te molebi kan nan ti won n jale

Owo iko Olopaa ipinle Ogun ti pada te Damilola Famoriyo eni odun merinlelogbon ati Akinbayo Emmanuel eni odun mokanlelogbon ti won je tegbon taburo ninu molebi kan na pelu esun pe ,won pa Ogbeni Amos Oyemechi leyin ti won gbe okada e lo
Adugbo Agoro nijebu ode nisele naa ti sele losu kejila odun to koja sugbon ti owo iko awon Olopaa ipinle naa ti te won nilu Ikorodu losu yii
Agbenuso olopaa ipinle Ogun iyen Oyeyemi fidi isele naa mule to si so pe,won ju oku Oloogbe segbe odo Agoro leyin ti won sa a pelu ada .O ti wa so pe awon tegbon taburo yii yoo foju bale ejo laipe


No comments:

Post a Comment

Pages