Ope o Abass Akande Obesere s'ile awosifila silu Ibadan - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, February 17, 2023

Ope o Abass Akande Obesere s'ile awosifila silu Ibadan

Gbogbo awon Ololufe Obaadan iyen Alaaji Abass Akande Obesere ni won ti n ki baba Junior ku oriire pelu bo se sile awosifila silu Ibadan
Oba Asakasa so pe,Ile molebi ni Ile naa pe oun ko o fun idile Ajalaruru ni,beeni oun ko Ile naa lati fi mu Inu awon obi oun dun ni,baba Suzan olowo Ori arewa obinrin to n je Sekinat Tolanikawo Adelakun ti wa so pe , oun dupe lowo awon molebi atawon Ololufe oun
Obaadan to sin omo lo sile oko lose to koja fi idunnu re han sawon molebi re ,idi eyi lo se pe oruko Ile to ko silu Ibadan naa ni'Ile Ajalaruru'
Ajalaruru yii loruko awon baba nla Obesere,sa o,Inu awon molebi Obesere n dun lasiko yii beeni gbogbo won ti n fi adura ranse si olowo Ori Tolanikawo.


No comments:

Post a Comment

Pages