Gege bi a se gbo pe,nitori baba ko ri owo gba,nibi to ti n fi ese run lo sibi ise re lati se eto lori redio Fresh fm Ibadan iyen redio Oloye Yinka Ayefele ni baba ti subu,ki awon ara agbegbe naa to gbe e de UcH Ibadan ni elemii ti gba a.
Tuesday, March 14, 2023
Baba Bintinlaye gbajumo sorosoro Ori redio jade laye
Ẹka Iroyin
# Isele Kayeefi
Pin-in Kaakiri
NIPA IROYIN TOJUBOLE
Isele Kayeefi
Labels:
Isele Kayeefi
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.

No comments:
Post a Comment