Yinka TNT yoo bale sorile ede yii laipe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Sunday, March 12, 2023

Yinka TNT yoo bale sorile ede yii laipe


Inu Gbogan Ostra nikeji ipinle Eko yoo mi titi lojo kejilelogun osu kerin odun yii nigbati arewa Obinrin to maa n soro nipa ibalopo nni iyen Yinka TNT yoo gunle sorile ede yii
Gbogbo eto lo ti wa to bayii nitori Obaadan iyen Alaaji Abass Akande Obesere, Akinola Dugbe ,Abbey Awesome,Saint Janet atawon olorin mi in yoo fori ki Yinka TNT kaabo sorile ede baba e
Fila ati aso polo lawon eeyan yoo fi wole lojo naa,e le pe awon nomba yii fun fila yin,08034752311,09091200467,08023299735

No comments:

Post a Comment

Pages