Egbe aborisa ni egbe oselu APC --Rhodes Gbadebo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, March 22, 2023

Egbe aborisa ni egbe oselu APC --Rhodes Gbadebo


Ogbeni Gbadebo Rhodes Vivour to je oludije sipo Gomina ipinle Eko labe Asia egbe oselu LP ti so loni in ojo weside pe,ojoro wa ninu eto idibo to koja nipinle Eko
O salaye pe, iyalenu lo je bi awon egbe oselu naa se n gbe ebo kiri gbogbo ibudo idibo ati pe ko si aniani ninu pe awon agbero yoo tun gbajoba lakotun
Sugbon o ti wa so pe, Oloye Bola Ahmed Tinubu ko le titori Ife to ni si oselu so gbogbo Eko di tire nikan ati pe ko leto lati maa pase pe dandan ni ko je egbe oselu APC ni yoo tun wole sipo Gomina
Ogbeni Gbadebo wa so pe, gbogbo awon to farapa lasiko idibo to koja ni egbe oselu LP yoo setoju beeni kawon olugbe ipinle Eko mo pe egbe to feran mekunnu ni egbe naa


No comments:

Post a Comment

Pages