Ikunle abiamo o,iya oko sun iyawo,omo e,atomoomo mole ni Akure - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Wednesday, March 22, 2023

Ikunle abiamo o,iya oko sun iyawo,omo e,atomoomo mole ni Akure


Akure nisele naa ti sele,a gbo pe iya Ogbeni kan to n je Victor ti sun un monu Ile,Koda iya yii sun iyawo omo e to n je Racheal atawon omo meji ti won bi monu Ile,esun pe won n fi ebi pa oun lo fi Kan won.

No comments:

Post a Comment

Pages