A gbo pe lojo ayeye ojo ibi iranse Olorun alaaye nni iyen Oludasile ijo Genesis Global , Oluso ati Wolii Oladele Ogundipe Genesis ni Ogbeni Adeniran Jandor to je oludije sipo Gomina labe Asia egbe oselu PDP nipinle Eko sare wo inu soosi oluso Genesis to wa ni isheri nipinle Eko lati lo gbadura ase latenu iranse Olorun naa
Jandor wa soro lojo naa loju gbogbo awon to wa nibi ayeye ojo ibi oluso Genesis pe,o da oun loju pe imo Olorun ni yoo se ninu aye oun lati di Gomina ipinle Eko labe Asia egbe oselu PDP
Oluso Oladele gbadura fun Jandor lojo naa topo awon to wa nibe si n so pe,igbagbo Jandor mu u larada ati pe bo se fi ohun gbogbo si owo Olorun lo

No comments:
Post a Comment