Gbogbo awon to ri bi Ogbeni White,to je omo Bibi Inu baba to ni bositoopu 'White House nitosi Ajasa Command ipinle Eko se jona mole ni won ti n pariwo ikunle abiamo
Oloogbe White ni iyawo re atijo ti ki n se pe obinrin naa bimo fun un Dana sun nigba to gbo pe Oloogbe ti n fe obinrin mi in,a gbo pe ati obinrin tuntun ati 'White Ni ika obinrin yii Dana sun mole ni ale ojo toside
Sa o, obinrin to Dana sun won yii ti salo sugbon ti emi ti pada bo lenu 'White ati Ololufe re tuntun

No comments:
Post a Comment