Oko Funke Akindele tele,ti segbeyawo pelu obinrin mi in - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, March 3, 2023

Oko Funke Akindele tele,ti segbeyawo pelu obinrin mi in

Falilat loruko iyawo tuntun ti Ogbeni Rasheed Bello topo mo si Jjc skills iyen oko gbajumo oseretiata obinrin nni to tun n dupo igbakeji Gomina ipinle Eko labe egbe oselu APC iyen Funke Akindele sese fe, ipinle Kano nigbeyawo bonkele naa ti waye sugbon ti asiri ti pada tu sita bayii pe, Ogbeni Rasheed ti n fe obinrin naa tipe


No comments:

Post a Comment

Pages