Ojo satide yii gan an nisele ajalu naa jalu idile Abacha,a gbo pe Abdulai ko saisan ko to lo sun lale ojo jimo sugbon ti ko ji mo laaro ojo satide,oun ni oloogbe Abacha bi,ki o to o bi abikeyin re.
Abdulai Abacha to je okan ninu awon omo Olori Orile ede yii nigba kan iyen Oloogbe Sani Abacha ti jade laye o

No comments:
Post a Comment