Inu ibanuje lawon oseretiata oloyinbo ati Yoruba wa bayii pelu bi iku se wole mu baba Mukaila Adedigba lo,ti iku naa tun wole were mu St Obi to je oseretiata oloyinbo lo
Ninu iroyin miiran la tun ti gbo pe,baba ijesha to je oseretiata okunrin aderinposo naa tun padanu baba re iyen pa James Arewa Omiyinka
Adura ti wa ni pe ki Olorun te gbogbo won safefe rere.
No comments:
Post a Comment