Ojo sannde niroyin naa gba igboro pe Murphy Afolabi to feran lati maa Se babalawo ninu fiimu Yoruba jade layeA gbo pe nise lo subu ninu baluwe re to si farapa yanna yanna ki won to gbe e de Ile iwosan elemii ti gba a.
No comments:
Post a Comment