Baba Asa lati orile ede Canada soro nipa ise ati Asa yoruba - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, June 16, 2023

Baba Asa lati orile ede Canada soro nipa ise ati Asa yoruba


Oloye Joel Oyaniyi Oyatoye to je baba Asa ti fi aidunnu re han Lori bii pupo ninu awon oba Alade se n ko iyan Asa ati ise kere lasiko yii
Oloye Joel to Fi orile ede Canada sebugbe ti wa be Aare Tuntun ti a sese fibo gbe wole lati mo pe,Omo Yoruba ponbele ti ko ye ki o ko Asa ati ise pelu igbelaruge Asa kere rara
O soro yii lasiko to gba egbe Akoroyin l'ede Yoruba lalejo nipinle Eko,to si tun fawon obi ati alagbato nimoran pe,Asa ati ise Yoruba ko gbodo parun.

No comments:

Post a Comment

Pages