Ope o!Alaaji Saheed Oluomo Kutonu sile awosifila silu Oshogbo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, June 3, 2023

Ope o!Alaaji Saheed Oluomo Kutonu sile awosifila silu Oshogbo

Gbogbo awon ololufe Alaaji Saheed Babatunde iyen Oluomo Kutonu ni won ti n ki i ku oriire ti Ile re to sese si si ipinle Osun to je ilu abinibi re
Opo awon to ri Ile awosifila yii ni won ti n ki baba alaanu awon oniroyin yii ku oriire,adura wa ni pe,emi Oluomo Kutonu yoo lo Ile naa gbo,beeni ki yoo sinku iyawo atawon Omo e sibe,kongratuleson Oluomo tia


No comments:

Post a Comment

Pages