Ojo ojobo ose yii ni odun Opo nipokia - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, June 27, 2023

Ojo ojobo ose yii ni odun Opo nipokia


Onipokia tilu ipokia nipinle Ogun iyen Oba ati Dokita Yisau Olusola Adeniyi Olaniyan Ilufemiloye Akoko,Akorede Orijajoogun Osingin keji yoo gbalejo awon eeyan Pataki kaakiri agbaye,ayeye odun OpO ti won maa n se nilu naa lo maa waye lojo toside iyen ojo ojobo ose yii
Alaaji Wasiu Alabi Pasuma yoo wa nikale lati forin da awon eeyan lara ya lojo naa nigba ti onje ofe pelu awon eto ti yoo se opo lanfaani naa yoo waye lojo naa pelu

No comments:

Post a Comment

Pages