Oloye Segun Showunmi ba egbe Akoroyin l'ede Yoruba so opo oro - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, June 27, 2023

Oloye Segun Showunmi ba egbe Akoroyin l'ede Yoruba so opo oro


Oloye Segun Showunmi to je Okan Pataki lara awon agbaagba ninu egbe oselu PDP nipinle Ogun ti so iru eeyan ti Oga re ninu egbe naa iyen Alaaji Atiku Abubakar je,lasiko ti Omo bibi ipinle Ogun naa n ba egbe Akoroyin l'ede Yoruba soro lo ti je ko di Mimo pe,Oloye Atiku je eeyan Olorun to si ni igbagbo pe,ojo ola Orile ede yii si maa dun gidi
Oloye Segun to tun je agbenuso ninu Oselu fun Alaaji Atiku ti wa gba Aare Tuntun iyen Aare Bola Ahmed Tinubu nimoran lati Mase je ki Iran Yoruba kabamo pe awon dibo fun un gege bii Aare Naijiria
Lasiko to n ba egbe Akoroyin l'ede Yoruba soro lo tun ti so pe,kawon eeyan tako iroyin tawon kan n gbe kiri igboro pe,alabosi ni oun nitori oun si n ba awon kan se ninu egbe oselu APC,o ni Iro to jinna si ooto loro naa sugbon ko seese ki oun ri awon agbaagba egbe oselu APC nigboro ki oun foju pa won re,ti oun ba lo ki won gege bii Omo Yoruba atata ko tumo si pe oun setan lati darapo mo won

Ju gbogbo e lo,Oloye Segun ti so pe,egbe oselu PDP si maa tuko orile ede yii pada,beeni ipinle Ogun gan an si ma je awon anfaani to Po gidi latodo egbe oselu PDP 

No comments:

Post a Comment

Pages