Aare Emmanuelking Adetola gba Oloja Epe nimoran - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, July 3, 2023

Aare Emmanuelking Adetola gba Oloja Epe nimoran


Ogbon ojo OSU to koja ni ayeye odun Ojude oba waye nilu Epe,ti alase Ileese Adrons,iyen ileese to n ba awon eeyan Ra Ile ati dukia si soju Gomina ipinle Eko Ogbeni Sanwo olu,nibe ni Aare Adetola Emmanuel King ti ro oba Epe, Oba Kamoru Isola Animashaun lati je ki irepo wa laarin awon Omo bibi ilu Epe kaakiri agbaye
Aare Emmanuelking Adetola so pe,yoo tun dara tawon olugbe ilu Epe ba gba awon ajoji laaye lati wa da ileese sile nitori yoo tubo je ki katakara rorun fawon olugbe ilu naa
Aare Emmanuelking to tun je Onile Aje tilu Epe ti wa je ko di Mimo pe,ileese oun ni awon Ile olowo pooku fawon mekunnu,nitori ore awon mekunnu ni oun.

No comments:

Post a Comment

Pages