O Mase o,won pa Omo Orile ede yii Danu ni Canada - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, July 3, 2023

O Mase o,won pa Omo Orile ede yii Danu ni Canada


Iwe ni odomokunrin to n je Oseke lo ka ni Orile ede Canada sugbon won ti pa a Danu lose to koja,adugbo Scarborough nisele naa ti waye,oyinbo toruko re n je Tamar Cupid lo seku pa Oseke ,sugbon ti owo Iko awon Olopaa orile ede naa ti te odaran to seku pa Omo Orile ede yii 

No comments:

Post a Comment

Pages